Home Orisirisi Awon dokita ni eegun Ronaldo si le bii ti omo ogun odun
Orisirisi - July 26, 2018

Awon dokita ni eegun Ronaldo si le bii ti omo ogun odun

Ayewo ti awon dokita egbe agbaboolu Juventus se lara Christine Ronaldo ti fihan pe o si ni eegn ati agbara to dab ii ti omo ogun odun.
Eyi tumo sip e oro Ronaldo kii se bii ti agbebo adie ti ko ni iwulo kankan mo.
Dipo bee, o si wulo ju awon asesejade agbaboolu miiran lo.
Awon dokita naa fi kun un pe ora ara re (fat) ko po rara, to tumo si pe ko kan le deede sanra jabata, ko wa maa se bii orobokibo lori papa.
Leyin wi pe Olorun fi ebun ke C-Ronaldo, o je elere idaraya kan to maa n tun ara re ko, to si n sise ju opo elegbe re lo.
Koda, ni World Cup to sese pari ni Russia, won ni oun lo sare julo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…