Home Orisirisi Ambode fe gba egberun tisa miran sise
Orisirisi - July 26, 2018

Ambode fe gba egberun tisa miran sise

Fun opo awon tisa ti won n wa ise ni Ipinle Eko, orin to ye ki won maa ko bayii ni orin ise de omo alaseje, owo ree omo alasela o.
Gomina Akinwunmi Ambode ti so pe ijoba oun ti setan lati gba egberun tisa miiran si ise, lati tubo mu ki ina eto eko maa jo geerege ni iawon ile iwe ipinle naa.
Ibeju Lekki ni Ambode ti gbe iroyin ayo naa jade, lasiko to n se ipade ilu-si-ilu pelu awon eniyan.
O tun mu u da won loju pe ijoba oun ko ni fi titun awon ohun meremere sere rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…