Home Orisirisi Omo Kunle Afolayan n kose mekaniiki
Orisirisi - July 25, 2018

Omo Kunle Afolayan n kose mekaniiki


Alara ni t’oun ara ni gbajugbaja onifiimu ti a mo si Kunle Afolayan.
Bayii, o ti ni ki akobi re, Damisire, maa ko ise mekaniiki.
Omo naa si ti bere ise naa gege bi e ti ri i ninu foto yii.
Sugbon sa o, fun iwonba igba ti omo naa wa ni olude olojo gbooro ni yoo fi ko o.
Afolayan ni oun se ipinnu yii lati je ki omo naa ni eko ise owo, ati bi lati wulo fun ara re ati fun awujo lojo iwaju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…