Home Orisirisi Oga olopaa Idris n ba Saraki fa surutu lori ole to ja ni Ofa
Orisirisi - July 24, 2018

Oga olopaa Idris n ba Saraki fa surutu lori ole to ja ni Ofa

Oga Olopaa ni orile-ede yii, Idris, ti so pe ki Aare Ile Igbimo Asofin, Dokita Bukola Saraki, o fara han ni olu ilea won olopaa to wa ni Abuja.
O ni Saraki ni lati wa so tie nu re lori bi de lara awon igara olosa to ja ni ilu Ofa laipe yii se so pe Saraki ni baba-nigbejo fun awon.
Sugbon sa o, Saraki so pe ija oselu, ija ilara lasan ni Idris n ba oun ja.
O ni won ti pe oun tele, ti oun si ti so ninu iwe ti oun fi ranse si won pe oun ko mo eni Kankan ninu awon ole naa.
Okan lara awon abanisise Saraki tile so laaro yii pea won olopaa ti wa moto dina ile oun, ti oun ko si raaye lo jade si ile oluuse awon agbofinro naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…