Home Orisirisi Fathia Balogun ko yoju sibi ojo ibi Dayo Amusa
Orisirisi - July 24, 2018

Fathia Balogun ko yoju sibi ojo ibi Dayo Amusa

O jo pe ija to wa laarin osere fiimu meji kan, Fathia Balogun ati Dayo Amusa, ko tii pari o.
Nnkan bii osu kan seyin ni gbonmi sii, omi o to o be sile laarin won.
Kinni naa le debi pe nigba ti Fathia lo se oku mama re, Dayo ko yoju sibe.
Boya idi niyi ti Fathia naa ko fi dara po mo opo alariya to lo ba Dayo Amusa naa se ayeye ojo ibi re to sese waye.
Ki Olorun ba won koore ambilii o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…