Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Bukola Saraki ati Dogara tun sepade miiran
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 24, 2018

Bukola Saraki ati Dogara tun sepade miiran

Aare Ile Igbimo Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, ti so pe oun ati Abenugan Ile Igbimo Asofin Kekere, House of Assembly, Onorebu Yakubu Dogara, sese se ipade kan tan ni.
O so ni ale oni pe awon sese jiroro lori bi eto isejoba tiwa-n-tiwa yoo se fese mule ni Naijiria ni.
Sugbon sa o, opo onwoye ni yoo ro pe o seese ki aluwaala oloogbo wa ninu ipade naa, eyi to je ogbon ati keran APC je.
Iru awn eniyan bee gba pe Saraki ati Dogara ti se ‘bai-bai’ si egbe naa ninu okan won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…