Home Orisirisi Uncle Davido ni PDP fa kale fun ibo gomina Osun
Orisirisi - July 22, 2018

Uncle Davido ni PDP fa kale fun ibo gomina Osun

Egbe PDP ti dibo yan Senito Ademola Adeleke gege bii oludije fun un nini ibo gomina to n bo laipe yii.
Eyi waye ni ojo keji ti APC yan Gboyega Oyetola ni oludije tiwon.
Ademola Adeleke ni aburi Isiaka Adeleke to ku ni nnkan bii odun kan seyin, to si je aburo baba akorin hip hop, Davido.
Nigba to soju PDP lati koju APC ninu ibo ati ropo Isiaka Adeleke, o gbeye lowo oludije APC nigba.
Boya eyi naa lo ta a nidii pee, to tun fi fe dije gomina.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…