Home LÁGBO ÀRÍYÁ O jigbijigbi! Moyo Lawal fi idi da Instagram ru
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - July 22, 2018

O jigbijigbi! Moyo Lawal fi idi da Instagram ru


Olorun Oba nikan lo mo ohun kan to fa idunnu nla fun onifiimu ti oruko re n je Moyo Lawal ni ale oni, eyi ti o mu u to fi bere si jo ijo judi-judi ninu fidio kan to gbe si ori ero alatgba Instagram.
Awada ni opo eniyan to n wo fidio naa koko pe e nigba ti Moyo bere ijo naa. Sugbon nigba ti o taari idi re rabata sita, ti o bere sii ju idi naa, ti idi re bere sii ku bi ojo, igba naa ni won wa mo kinni naa loran gidi.
Opo awon to fi gbolohun ranse sii lori ijo yodi-yodi naa ni won kan saara sii.
Awon okunrin kan tie ni awon fe rii ni idakonko, bi o tile je pea won kan lodi si ere gele ti o se naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…