Home òpómúléró Uncle Davido fe ba APC fa surutu lori ibo gomina ni Osun
òpómúléró - July 21, 2018

Uncle Davido fe ba APC fa surutu lori ibo gomina ni Osun

Egbe PDP ti dibo yan Senito Ademola Adeleke gege bii oludije fun un nini ibo gomina to n bo laipe yii.
Eyi waye ni ojo keji ti APC yan Gboyega Oyetola ni oludije tiwon.
Ademola Adeleke ni aburi Isiaka Adeleke to ku ni nnkan bii odun kan seyin, to si je aburo baba akorin hip hop, Davido.
Nigba to soju PDP lati koju APC ninu ibo ati ropo Isiaka Adeleke, o gbeye lowo oludije APC nigba.
Boya eyi naa lo ta a nidii pee, to tun fi fe dije gomina.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…