Home iroyin Òjóró lè má jẹ́ kí ẹgbẹ́ wa kópa nínú ìbò 2019 – PDP
iroyin - July 21, 2018

Òjóró lè má jẹ́ kí ẹgbẹ́ wa kópa nínú ìbò 2019 – PDP

Alagba Kola Ologbodiyan to je akowe agba fun egbe oselu PDP lo n ba awon oniroyin soro ni ilu Abuja pe, ti awon ba rii pe ojoro ko ni je ki ibo odun to n bo yanju, egbe oselu awon le ma kopa rara nitori ibi ti ojoro ibo ba ti po maa n da omi tutu si okan awon oludibo ati oludije ni.
Ologbodiyan ni ti o ba ti wa di wi pe egbe oselu awon ko kopa ninu idibo gbogbogbo, eyi maa han si gbogbo aye pe ko si ibo ni orileede yii. Eyi ti o lodi si eto omoniyan ati ofin ile wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…