Home Orisirisi N ko gba owo lowo sugar daddy kankan – Liz Anjorin
Orisirisi - July 21, 2018

N ko gba owo lowo sugar daddy kankan – Liz Anjorin

Gbajumo onifiimu Liz Anjorin, ti so pe ko si sugar dady Kankan to n fun oun ni owo.
O ni gbogbo dukia ti oun ni, lati ara oogun oju oun lo ti wa.
O ni laaro ati ale, oun sise asekara, oun si ni orisiirisii okowo to n mu owo wole fun oun, tori oun mo pe ko si owo kan dabi alara nidii ise fiimu.
O ni awon ajifiimuta – pirates – ko je ki awon onifiimu maa ri ere.
Koda, o ni afaimo ni ki ise fimu sise ma wo lule ni Naijiria laipe, tori awon olokoowo to lowo kii fi owo sibe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…