Home iroyin Owo olopaa te Olayemi to ti ji moto mejilelogbon gbe
iroyin - July 20, 2018

Owo olopaa te Olayemi to ti ji moto mejilelogbon gbe

Owo awon olopaa Ipinle Ondo ti ba okunrin kan ti oruko re n je Olayemi Adeoye, eni ti won ni o je ogbologbo ole to n ji moto.
Olu ile ise olopaa Ondo ni Adeoye ti wa ninu ise naa lati ojo to tip e.
Gege bi Alukoro olopaa ipinle naa se so, Alagba Femi Joseph, se so, o to moto mejilelogbon (32) ti Adeoye ti ja gba mo awon to ni won lowo.
Koda, o ni moto Honda lo feran ju lati maa gbe.
Joseph ni awon olopaa ti maa n gba Adeoye mu tele, to si je pe o maa n gba itusile ni ile ejo.
Adeoye ati awon alabasisepo re meji – Waheed Anifowoshe ati Paul Ayeni – ni owo ba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…