Oyetola Isiaka ni APC dibo yan gege bi oludije gomina
Esi ibo ti egbe APC di lonii ati yan eni ti yoo soju won ninu idibo gomina to n bo yii ti jade.
Oloye Oyetola Isiaka ni Ifa awon oludibo mu.
Okunrin naa ni opo eniyan ti foju si lara tele, nitori bi o se sun mo Asiwaju Bola Tinubu ati Gomina Rauf Aregbesola.
Se Yoruba ni a kii leni ni Musan, ka mu kikan.
Bi esi ibo naa se lo ni eyi:
Ayedade LGA
Salami Najeem- 459
Yusuf Lasun- 632
Oyetola Isiaka- 3, 735
Atakunmasa West LGA
Salami Najeem- 344
Yusuf Lasun- 566
Oyetola Isiaka- 3, 916
Isokan LGA
Salami Najeem- 224
Yusuf Lasun- 341
Oyetola Isiaka- 2, 120
Olorunda LGA
Salami Najeem- 301
Yusuf Lasun- 1, 224
Oyetola Isiaka- 4, 699
Orolu LGA
Salami Najeem- 772
Yusuf Lasun- 1, 243
Oyetola Isiaka- 3, 130
Boripe LGA
Salami Najeem- 0
Yusuf Lasun- 241
Oyetola Isiaka- 5, 945
Atakunmasa East LGA
Salami Najeem- 429
Yusuf Lasun- 689
Oyetola Isiaka- 8, 469
Ayedire LGA
Salami Najeem- 50
Yusuf Lasun- 351
Oyetola Isiaka- 1, 537
Irepodun LGA
Salami Najeem- 22
Yusuf Lasun- 1, 977
Oyetola Isiaka- 2, 337
Ife South
Salami Najeem- 86
Yusuf Lasun- 498
Oyetola Isiaka- 6, 410
Iwo LGA
Salami Najeem- 229
Yusuf Lasun- 718
Oyetola Isiaka- 2, 525
Ife North LGA
Salami Najeem- 331
Yusuf Lasun- 493
Oyetola Isiaka- 2, 926
Ifedayo LGA
Salami Najeem- 392
Yusuf Lasun- 668
Oyetola Isiaka- 1, 841
Ife East LGA
Salami Najeem- 121
Yusuf Lasun- 393
Oyetola Isiaka- 5, 423
Oriade LGA
Salami Najeem- 135
Yusuf Lasun- 555
Oyetola Isiaka- 7, 410
Ife Central LGA
Salami Najeem- 5
Yusuf Lasun- 1, 737
Oyetola Isiaka- 4, 977
Ilesha West LGA
Salami Najeem- 35
Yusuf Lasun- 0
Oyetola Isiaka- 5, 893
Boluwaduro LGA
Salami Najeem- 134
Yusuf Lasun- 374
Oyetola Isiaka- 3,214
Ede North LGA
Salami Najeem- 223
Yusuf Lasun- 525
Oyetola Isiaka- 3, 008
Egbedore LGA
Salami Najeem- 588
Yusuf Lasun- 561
Oyetola Isiaka- 1, 161
Osogbo LGA
Salami Najeem- 650
Yusuf Lasun- 1, 923
Oyetola Isiaka- 7, 084
Irewole LGA
Salami Najeem- 0
Yusuf Lasun- 343
Oyetola Isiaka- 4, 023
Olaoluwa LGA
Salami Najeem- 181
Yusuf Lasun- 445
Oyetola Isiaka- 2, 209
Ilesha East
Ismaila Abiodun- 12
Adeleke Oriolowo- 106
Isiaka Oyetola- 7, 365
Najim Salami- 74
Yusuf Lasun- 306
Ejigbo LGA
Salami Najeem- 10, 569
Yusuf Lasun- 80
Oyetola Isiaka- 8
Obokun LGA
Salami Najeem- 286
Yusuf Lasun- 896
Oyetola Isiaka- 7, 434
Ifelodun LGA
Salami Najeem- 119
Yusuf Lasun- 1153
Oyetola Isiaka- 4, 075
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…