Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Segun Odegbami fe dije fun ipo gomina ni Ogun
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 18, 2018

Segun Odegbami fe dije fun ipo gomina ni Ogun


Idije fun ipo gomina ni Ipoinle Ogun ti fe ba ona ibomiran yo o.
Agbaboolu ara tele, Oloye Olusegun Odegbami, ti kede pe oun yoo dije fun ipo naa.
O ni oun ti setan lati darapo mo egbe Labour Party, ti oun yoo si gbe apoti loruko egbe naa.
Eyi tumo sip e o fe figa gbaga pelu awon ti won ti n pete ati dije ninu io naa ti yoo waye ni 2019.
Lara won ni Olamilekan Yayi, Gboyega Isiaka ati Lanre Tejuosho.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…