Home iroyin Ayederu dokita seku pa eniyan meji
iroyin - July 18, 2018

Ayederu dokita seku pa eniyan meji

Awon eniyan meji kan ti kagbako ni Ipinle Ondo, nigba ti won lo si ile iwosan okunrin kan lati gba itoju.
Alaafia ati iye ni won wa lo si ‘osibitu’ naa ti o wa ni ibi kan ti won n pe ni Uso, sugbon iku ni won ri nibe.
Idi ni pe iro ni okunrin naa ti oruko re n je Adewale Emmanuel Owolanke pa pe doita ni oun.
O paro pe oun kekoo gboye ni Barbados, o si tun so pe oun n kekoo lowo ni ifafiti ti Benin.
Gege bi awon alase ile ise eto ilera Ministry of Health se so, opo eniyan ni okunrin naa ti se ijamba fun.
Odo awon olopaa ni Adewale wa bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…