Home Orisirisi Pasuma ge fila genge nibi Nikai omo MC Oluomo
Orisirisi - July 16, 2018

Pasuma ge fila genge nibi Nikai omo MC Oluomo

Nnkan bi osu meji ti okan lara awon omo ogunna gbongbo ninu egbe awon onimoto, iyen Alhaji Musiiu, ti opo eniyan mo si MC Oluomo, ka iwe gboye ni orile-ede America, nnkan ayo si n sele nile re ni o.
O sese se Nikai fun omobinrin re kan, Ayisat Adufe Akinsanya, nibi ti opo eniyan ti lo ba MC Oluomo se ajoyo.
Lara won ni onifuji pataki, Wasiu Alabi Pasuma, eni to ge fila genge lo sibe, awon olori onimoto, oloselu ati bee bee lo.
Pelu idunnu ni MC Oluomo fi n dupe lowo gbogbo awon ti won sugbaa re, to si n yin Olorun logo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…