Home Orisirisi Mo maa dan mewaa wo ni Juventus – Ronaldo
Orisirisi - July 16, 2018

Mo maa dan mewaa wo ni Juventus – Ronaldo

Agbaboolu agbayanu ni, Christine Ronaldo, ti se ileri pe oun yoo se bebe ni Juventus.
O ti darapo mo egbe agbaboolu naa, to si ti gba aso jersey won.
O ni oun yoo fi han awon to wa ni Juventus ati ni gbogbo agbaye pe oun si le se awon ohun meremere ti oun se ni Manchester United ati Real Madrid.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…