Home ERÉ ÌDÁRAYÁ France foju Croatia gbole (4-2)
ERÉ ÌDÁRAYÁ - Orisirisi - July 15, 2018

France foju Croatia gbole (4-2)

Ko si ohun to ni ibere ti ko ni opin. Ere boolu ife agbaye to bere ni aipe yii ti dopin lonii ojo keedogun osu keje odun ti a wa yi.
Orileede mejilelogbon lo bere ere boolu naa, kere-kere, won ku merindinlogun. Igba to ya, o ku mejo, mejo tun ku merin. Awon orileede merin yii ni won to gbangba sun ninu oye. Ninu awon merin yii ni orileede France ti na England nigba ti Croatia naa gbo ewuro si oju Belgium. Awon mejeeji ti won na ba ara won gba, orileede Belgium sin a Enland ni ami ayo meji si odo ni ana ojo kerinla, osu keje odun yii. Awon mejeeji to yege yii ni won wako ni ojo asekagba ti orileede France si ba Croatia wi peluu ami ayo merin si meji. Ninu meji ti orileede Croatia gba wole France ni eedi kan ti mu goli France, bi bee ko eyokan pere ni Croatia ko ba gba wole France, bi o tile je pe ara ija naa ni eyin wa.
Orileede France gbe ife eye RUSSIA 2018 lole. Gbogbo aye sib ere sin i ki won ku oriire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…