Home Orisirisi FAYEMI jawe olubori, o fi agba han Eleka!
Orisirisi - July 15, 2018

FAYEMI jawe olubori, o fi agba han Eleka!

Leyin opolopo ariwo ati aroye, o ti daju bayii pe Dokita Kayode Fayemi ni gomina tuntun ni Ipinle Ekiti.
Ninu esi idibo ijoba ibile merindinlogun ti INEC ti gbe jade, Fayemi siwaju alatako re to gbona julo, Eleka.
Eyi tumo sip e ija nla to sele laarin APC ati PDP lori idibo naa, owo APC lo fe ja si.
Sugbon Gomina Ipinle Ekiti lowolowo yii, Ogbeni Ayodele Fayose, gba pe oro ko ri bee.
Boya idi niyi to fi lo sori redio ipinle naa, to si kede pe Eleka lo wole.
Ijoba apapo ti fi ilodi si re han lori eyi, to si ti ti ile ise redio naa pa.
Idibo Ipinle Ekiti naa je eyi to ko opo eniyan lominu, latari bi won se so pe egbe ejeeji pin owo fun awon oludibo loju koroju.
Bee, egbe PDP ati APC naa si n fie sun kan ara won pe won seru ibo.

ESI IDIBO NLA NAA

APC 197,460
PDP 178,114.

Bi o se lo ni awon ijoba ibile:
(1) Ilejemeje LGA
APC – 4,153
PDP – 3,937
(2) Ido-Osi LGA
APC- 12,342
PDP- 11,145
(3) Oye LGA
APC – 14,995
PDP – 11,271
(4) Efon LGA
APC – 5,028
PDP – 5,192
(5) Moba LGA
APC – 11,837
PDP – 8,520
(6) Ijero LGA
APC – 14,192
PDP – 11,077
(7) Irepodun/Ifelodun LGA
APC – 13,869
PDP – 11,456
(8) Gbonyin LGA
APC – 11,498
PDP – 8,027
(9) Emure LGA
APC – 7,048
PDP – 7,121
(10) Ikere LGA
APC – 11,515
PDP – 17,183

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…