Home Orisirisi Idi ti mo fi kiisi RMD – Dakore Egbuson-Akande
Orisirisi - July 14, 2018

Idi ti mo fi kiisi RMD – Dakore Egbuson-Akande


Osere Nollywood, Dakore Egbuson, to ti n je Dakore Akande bayii leyin to se igbeyawo, ti se alaye idi to fi gbenu ko osere miiran Richard Mofe-Damijo, lenu lemolemo ninu fiimu tuntun kan, The Castle and Castle.
Bi awon mejeeji se kiisi ninu fiimu naa lagbara debi pe opo eniyan to ba wo o yoo fee maa to si ara.
Abileko ni Dakore, bee RMD naa kii se apon. Oun ni bale Jumobi Adegbesan.
Dakore ni bi oun ba maa se ere naa daadaa, ko si bi awon ko se ni kiisi bee.
O ni oun tun jerii RMD, tori kii se omode ninu ere fiimu.
Bakan naa, Dakore ni oun gba ase lowo oko oun lati kopa ninu ere naa ati lati kiisi RMD.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…