Ibo pari ni Ekiti, Fayemi ati Eleka bori ni woodu won
Esi ibo lo ku ti a n reti lati Ipinle Ekiti bayii, leyin ti ibo didi ti pari.
A gbo pe awon egbe oselu mejeeji ti won wa niwaju pin owo fun awon oludibo nibi kan.
Won pin to egberun naira meta si mesan-an nibo miran.
Bi a se wa n reti ki INEC ka ibi ko sig be esi jade, awon eniyan kan ti n fi awon esi kan sori ero alatagba, to si je pe Olorun lo mo eni to n so otito.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…