Home ERÉ ÌDÁRAYÁ CHELSEA GBA ISE LOWO CONTE, WON BA GBE FUN MORIZIO SARRI !
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 14, 2018

CHELSEA GBA ISE LOWO CONTE, WON BA GBE FUN MORIZIO SARRI !

CHELSEA GBA ISE LOWO CONTE, WON BA GBE FUN MORIZIO SARRI !
– Akinwale Taophic.
Owe Yoruba ni o so wi pe ko si oun ti o ni ibere ti ko kii ni opin, leyin odun meji ati osu meta gege bi olukoni fun egbe agbaboolu Chelsea, ise bo lowo Antonie Conte gege bi olukoni fun egbe agbaboolu Chelsea ni ale ojobo ose ti o ko ja lo yii leyin ti o gba liigi orileede England ati FA Cup fun won ni igba kookan, ni esekese ni won si ti kede olukoni egbe agbaboolu Napoli tele ri, Maurizio Sarri, gege bi olukoni tuntun fun ipo naa ti ise re si ti bere ni esekese.
Maurizio Sarri, eni ti Gianfranco Zola je igbakeji re lowo bayii ninu iko Chelsea, ko ti gba ife eye kankan ri gege bi olukoni sugbon o ti ni iriri ti o po.
Gege bi owo gba ma binu wi pe a da e duro, igbimo ti o n se akoso egbe agbaboolu Chelsea fun Conte ni owo re ti o ku ni inu adehun won eyi ti o n lo bi milionu mesan-an poun owo ile okere (£9 million), ki won o to dagbere fun wi pe o di igbakan naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…