Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mide Martins dupe lowo Olorun lori omo re to kawe jade
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 12, 2018

Mide Martins dupe lowo Olorun lori omo re to kawe jade

Sinkin ni inu osere fiimu, Mide Martins, n dun bayii, tori omo re ti oruko re n je Aanuoluwapo sese pari eko re ni MD School, ni agbegbe Ojodu Berger ni ilu Eko ni.
Orin ope ni Mide fi bo enu. O n so fun Olorun pee nu oun ko gba ope, ete oun ko gba iyin, ati pe oun ko tie mo eyi ti ko ye ki oun dupe fun lori gbogbo oore ti Olorun se fun oun.
Mide gboriyin fun Aanuoluwapo naa. O ni inu oun ati bale oun, iyen Afeez Owo, dun pupo pe omo nag be ogo idile awon ga.
Bayii, ile iwe girama o ku ki omo naa lo. Ki Olorun tubo maa se alaabo ati olugbega re. Amin ati awon omo tiwa naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…