Èmi ò kì ń jalè, jìbìtì lásán ni mo ń fi káàdì ọlọ́pàá ṣe
Ọwọ awon olopaa ti te Mahmuda Hamza to n fi olopaa lu jibiti kaakiri ilu. Ni igba ti owo te lo bere si ni ka boro-boro. O ni kaadi idanimo olopaa kan to ku ni oun kan yo foto re danu ti oun si fi ti oun sii. O ni oun ko lowo ninu iku re rara.
Mahmuda be awon olopaa ki won jowo ma se gbe oun lo ile-ejo tabi ki won fi iya kankan je oun nitori pe oun ko ki n pa eniyan tabi ja ole. O ni ninu ise jibiti naa ni oun ti n bo iyawo meji ati omo meje.
Awon olopaa ipinle Sokoto ni ki olomo o kilo fun omo re ni ipinle naa nitori pe ko si aaye fun iwa jibiti tabi egbe okunkun rara.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…