O kasiara! Genevieve pari estate to ko si Abuja
Eni to ba n foju kekere owo wo osere fiimu ti a mo si Genevieve Nnaji, oluware ko nikan se ni o.
Oro ti wa foju han pe owo nla n be ni owo re, to si je pe kii se ipapanu lo n fowo re je.
Arabinrin naa ti pari ile rere alagbeta ti a mo si estate ni Abuja.
Pelu idunnu I o fig be foto ibe jade, ti awon ololufe re si n kan saara si i.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…