Home iroyin E ku ewu omo o! Zahra omo Buhari bi omobinrin lanti-lanti
iroyin - July 10, 2018

E ku ewu omo o! Zahra omo Buhari bi omobinrin lanti-lanti

Idunnu ti subu layo nile Aare Muhammadu Buhari, tori omobinrin re, Zahra, sese bi omobinrin lanti-lanti ni.
A gbo pe orile-ede Spain lo bimo si.
Igbati Aare Buhari ti de ipo naa ni Zahra se igbeyawo, ti Olorun si ti da oun ati baale re, loun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…