Home iroyin O ti jade o! awo orin melaye tuntun
iroyin - July 9, 2018

O ti jade o! awo orin melaye tuntun

Seneto Dino Melaye to n soju ipinle Kogi to gbe awo orin meji jade sugbon eyi to gbaju-gbaja ju ni “ajekun iya ni yoo je ”. Bayii ni Seneto yii tun ti gbe omiran jade to ni lati se pelu ede aiyede to wa laarin egbe re APC ati PDP.
Melaye ni oun ni lati lo si ibi ti won ti n fe oun ti won si n fe bukata oun, koda alagba Femi Fani Kayode ti n kii ninu ero ayelujara pe o kaabo si inu egbe re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…