Home iroyin Fayemi fesun ibaniloruko je kan Fayose
iroyin - July 9, 2018

Fayemi fesun ibaniloruko je kan Fayose

Ipolongo ibo to gbona janjan si n lo lowo ni ipinle Ekiti bayii. Ibe naa ni awon olutele Fayemi ti feti koo bi Fayose se n polongo ibo pe ki awon ara ilu ma se dibo fun Kayode Fayemi ti egbe oselu APC nitori ti o ba lo wole ibo gomina to dije re ni ose to n bo ni ojo kerinla osu yii, a je wi pe awon Fulani daran-daran kan maa pa won bi eran ni, nitori pe Fayemi maa faaye gba won. Won ni Fayemi ni ki won yaa dibo won fun egbe oselu PDP jeje won.
Eyi bi awon olutele Fayemi ninu, won si kilo fun egbe oselu PDP lati ma se da ilu Ekiti ru rara. Ki eto idibo le lo ni irowo ati irose.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…