Home Orisirisi Dayo Amusa n beere pe ta lo maa n gbadun ibalopo ju larin okunrin ati obinrin
Orisirisi - July 9, 2018

Dayo Amusa n beere pe ta lo maa n gbadun ibalopo ju larin okunrin ati obinrin

Bi osere fiimu Dayo Amusa ba maa ko iwe kan, o seese pe lori ibalopo okunrin ati obinrin ni yoo ko iwe naa le.
Ohun ti o f aero yi ni bi o se so oro ijinle lori ibara eni sun, ti o si ni ki awon eniyan maa so ero tiwon naa.
Bi o tile je pe Dayo Amusa ko tii se igbeyawo, o soro ijinle lori ipa ti biba ara eni lopo n ko laarin oko ati iyawo.
Gege bi o se so, inu igbeyawo ti ayo ati alaafia ba wa, took-tiyawo ibe maa n gbadun ibasun daadaa.
O ni ibara eni sun deede naa maa n da kun alaafia loko-laya.
Dayo Amusa tun wa beere pe ta lo maa n gbadun ibasun ju laarin okunrin ati obinrin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…