Home Orisirisi APC yari mo R-APC lowo, awon olori PDP n sepade lonii tori Atiku, Saraki, Marakarfi, Dogara
Orisirisi - July 9, 2018

APC yari mo R-APC lowo, awon olori PDP n sepade lonii tori Atiku, Saraki, Marakarfi, Dogara

Awon egbe oselu bii APC, R-APC ati PDP ti bere sii maa gbe e gbona funra won o. Eyi si ni apere ohun ti a yoo maa ri titi di 2019.
Ni akoko, egbe APC ti fonmu mo R-APC lowo. O ni R-APC ko le so oruko APC di yeleyele, ati pe ona ti awon olori egbe naa fi ko ara won jo, ti won fey a danu ko ba ofin mu.
Gege bii Looya Agba un APC, Alagba Babatunde Ogala, se so, APC maa gbe awon R-APC lo si kootu.
Bi APC se n se eyi ni awon R-APC naa n n sepade tosan toru. Bakan naa, awon olori PDP yoo se ipade kan ni Abuja lonii, lati mo ona ti won yoo fi lepo pelu pelu R-APC.
Ni Ipinle Ekiti naa nko? Dokita Fayemi ati Ogbeni Ayodele si n dun mohuru mohuru mora won ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…