Home LÁGBO ÀRÍYÁ Joke Silva n mura sile fun igbeyawo omo re
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 8, 2018

Joke Silva n mura sile fun igbeyawo omo re


Sinkin ni inu gbajugbaja onifiimu, Joke Silva, n dun bayii, tori ko nip e di Grandma.
Omo re, Olusoji, yoo se igbeyawo laipe yii, eyi ti a gbo pe yoo larinrin gan-an ni.
Joke Silva ko le fi idunnu re pamo nigba to n se ikede igbeyawo naa lori ero alatagba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…