Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Iro abi ooto? Fayemi ni awon osise ijoba Ekiti ko tii gba owo osu kankan lodun yii
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 8, 2018

Iro abi ooto? Fayemi ni awon osise ijoba Ekiti ko tii gba owo osu kankan lodun yii

Oludije ipo gomina fun egbe APC nin ibo ojo Satie, Dokita Kayode Fayemi, ti so pe osise ijoba Kankan ko tii gba owo osu ni ipinle naa ni odun yii.
Bee, o ni awon osise feyinti ko tii gba kobo lodun yii.
Ninu iforowanilenuwo kan, Fayemi niiru inira bayii ti ijoba Ayo Fayose ko baa won eniyan ni oun fe mu kuro, I oun fi fe di gomina leekan sii.
O se afikun re pe ko si ninu erongba oun lati da awon tisa duro, bee oun ko ni ki olokada ma rinna.
O ni oun ti oun ni lokan ni ki won maa lo akoto lati daabo bo emi won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…