Home Orisirisi Eemo ni ilu Akure! Won ba oku omo igbakeji gomina ana labe beedi ololufe re!
Orisirisi - July 8, 2018

Eemo ni ilu Akure! Won ba oku omo igbakeji gomina ana labe beedi ololufe re!

Ajalu nla kan ti de ba Igbakeji Dokita Olusegun Mimiko nigba to je gomina, Alhaji Lasisi.
Omobinrin re kan ti oruko re n je Adenike, ti o je omo ile iwe Adekunle Ajasin University ni o ti pade iku ojiji.
Won ba oku re labe beedi ololufe re kan ti won pe oruko re ni Adeyemi Alao.
Bawo ni oku Adenike se de ibe? Eyi ni ibeere ti awon olopaa Ondo n gbiyanju ati dahun bayii, tori Alukoro Olopaa ni ipinle naa, Alagba Femi Joseph, ti ni otito ni isele naa sele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…