Home Orisirisi Ni aadota odun, Mosun Filani si n dan loju gbere
Orisirisi - July 6, 2018

Ni aadota odun, Mosun Filani si n dan loju gbere


Enu si n ya opo eniyan to mo osere fiimu, Mosun Filani, ni o. Idi nip e won ko mo pe o ti to eni aadota odun. Bee, o si n dan loju gbinrin ni o, bi opa wolii.
Sugbon obinrin naa ti fi idunnu ati ayo so fun araye pe oun ti de ibi ojo ori ti awon oloyinbo n pe ni golden age – iyen aadota odun (50)
Eyi tumo si pe Mosun kii se egbe opo awon osere ti a le maa ro pe won sun mo ara won lojo ori.
Lara won ni Funke Akindele, Mercy Johnson ati Iyabo Ojo, to je pe won sese pe ogoji odun ni.
Mosun naa mo pee nu yoo ya awon eniyan kan nigba ti won ba gbo pe oun tip e eni aadota odun.
Ninu atejade kekere to se lori ero alatagba, o ni bale oun gan an mo pe oun ti di eni aadota odun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…