Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Injuri Cavani se akoba fun Suarez. Uruguay se BYE BYE si Word Cup
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 6, 2018

Injuri Cavani se akoba fun Suarez. Uruguay se BYE BYE si Word Cup

Egbe agbaboolu France ti le Uruguay jade ni World Cup to n lo lowo ni Russia.
Ami ayo meji si odo ni won ko le won lowo.
Bi o tile je pe golikipa Uruguay lo nagere ti goolu keji fi wole, injuri ti ogunnagbongbo agbabooly Uruguay, iyen Edinson Cavani, ni lo jo pe o se akoba julo fun won.
Oun ati Suarez mo owo ara won pupu, sugbon ko kopa rara niu iije ti irole yii.
Eyi je ki Suarez o maa gba boolu bi eja ti won ti mu kuro ninu odo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…