Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Ofon-on to si gbegiri, Saraki, Dogara fi APC sile fun Buhari ati Tinubu
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 5, 2018

Ofon-on to si gbegiri, Saraki, Dogara fi APC sile fun Buhari ati Tinubu

Irin n be lese baba alajo Aare Muhammadu Buhari ati awon olori egbe APC miiran bii Asiwaju Bola Tinubu pelu Alagba Adams Oshiomhole o, tori awon omo egbe pataki kan ti n fi won sile.
Won ti da egbe miiran sile, ti won pe ni Reformed APC.
Oruko naa ranni leti Reformed Ogboni Fraternity, bi o tile je pe won kop e ara won ni olOgboni.
Pelu bi nnkan se n lo, o seese ki won parapo mo egbe ti Oloye Olusegun Obasanjo n da sile, to si je pe won le darapo mo Atiku naa.
Ti won ba se bee, o jo pe won a fun Buhari ni wahala die lasiko ibo to n bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…