Home Orisirisi Gani Adams fariga lori aabo ile Yoruba
Orisirisi - July 5, 2018

Gani Adams fariga lori aabo ile Yoruba

Awon agbaagba ni, ‘Aare Ona Kakanfo n pale ogun mo, oosa oke ma je ko tenu mi jade!’ Gege bee ni orin to ye ki eniyan maa ko bayii, lori igbese kan ti Aare Ona Kakanfo ile Yoruba, Otunba Gani Adams, n gbe lori aabo ile Yoruba.
O ti gbe atejade kan sita pe oun ati awon agbaagba ile Oodua ko gbodo laju sile ki talubo ko si i lori bi awon alakatakii, apaniyan, awon oniwahala darandaran se n dogbon wo ile Yoruba.
Latarii eyi Aare ti n seto lori ipade nla kan ti won yoo se lati daabo bo Yoruba.
A gbo pea won agbekoya naa yoo kopa ninu ipade naa.
Gbogbo bi o ba se n lo, gbogbo re naa ni IROYIN OWURO yoo maa fi to yin leti.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…