Awa ti a maa kuro ni APC po pupo – Sheu Sanni
Okan lara awon asofin agba APC, Senito Sheu Sanni, ti so pe awon ti awon maa kuro ni egbe APC kii se keremi.
Ni bayii, won ti da egbe miiran sile ti won pe ni Reformed APC, nibi ti awonBukola Saraki, Yakubu Dogara ati awon olori egbe APC miiran wa.
Sanni tun ti so bayii pe keese-keese ni a ri ti a n wi, kaasa-kaasa n bo lona – kaasa-kaasa baba leese-keese.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…