Tonto Dike n wa okunrin ti yoo maa di ara won mu
Gbajugbaja onifiimu Nollywood, Tonto Dike, kii se eni kan to maa n fi owo to n dun un boa be aso.
Dipo bee, o maa n so bi oro se kan an gan-an ni.
Ni bayi, o ti ke gbajare pe oun n wa eni ti yoo maa ko oun mora, ti yoo maa ba oun sere ife.
Idi ni pe igbeyawo re ti daru, I oun ati oko re si ti fi ara won sile leyin to bimo kan fun un.
Ohun ti Tonto Dike n so un araye tele ni pe latigba ti ti oun ti kuro nile bale oun, oun ko tii ba okunrin kan ni ajosepo.
O ni danfo gedegbe ni oun wa, ti oun si fi ara oun sile fun Olorun.
Sugbon bayii o, o jo pe orin body-no-be-wood lo fe ko, to si n so lati okan re pe oun n wa eniyan ti awon yoo jo maa sa-prapra – bi asa kan ti won n da lode oni. Ori ero alatagba lo ti se eyi, nibi to tipa kinni naa bi owe ‘cuddle’.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…