Bi igba ti mo wa ni ogba ewon lo ri nigba ti mo sanra yokoto – Lepacious Bose
Obinrin alawada ti a mo si Lepacious Bose ti ranti igba kan to je orobo-kiboo.
Ni nnkan bii odun meta seyin lo dogbon si i, ti oun naa si ti le daragbe bayii.
O ni lasiko naa, o da bi igba ti oun wa ni ogba ewon ni, tori inira gidi ni ara sisan bokoto mu fun un.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…