O ga ju! Aare Buhari n se YUPPY ni Mauritania
Bi Don Jazzy tabi awon ewe iwoyi bar o wi pe won nikan la won mo bi won se n lo foonu igbeseti ti a mo si head phone, won kan n tan ara won je ni o.
Won ni lati ri bi Aare Muhammadu Buhari naa se gbe ohun elo igboran ati atumo ede seti ni orile-ede Mauritania, nibi to ti wa ninu ipade awon olori orile-ede Afirika ti a mo si African Union Summit.
Baba Buhari, Eyoo o!
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…