Fanikayode so kobakungbe oro si Osinbajo
Minisita fun Oro Ko Ofurufu tele, Oloye Femi Fanikayode, ti so oro buruku si Igbakeji Aare Orile-ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo.
Asoro-faa ti n je Fanikayode n binu si Osinbajo lori esi to so pe igbakeji aare so lori awon ti Fulani pa ni Plateau ati awon ipinle miiran.
Gege bi o se so, o ni Osinbajo so pe Ijoba Apapo maa fun won lowo gba-ma-binu.
Fanikayode ko ri ri igbese bee bii eyi to dara rara.
O wa soro buruku lori ero Twitter re si Osinbajo.
O ni ara lapalapa ko ya rara – tori a ko gbodo daruko igbakeji aare gege bi oun se se.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…