Kadara yan Messi je: Ko m’ori Wold Cup waye
Yoruba bo, won ni Lanintan kan ko niwo esin. Gege bee ni ti meriiri agbaboolu ti a mo si Lionel Messi je.
Bi o tile je pe o ti gba gbogbo irawo ninu idije bii La Liga ati Champions League, to n da bi edun to n ro bi owe ni Barcelona, oriboriye bii agbado eerun ni oro re ninu egbe agbaboolu Argentina.
Ni pataki, bi irawo re se tan to, ko ri Wold Cup gba.
Pelu ohun to si sele ni irole yii, boya ni yoo fi ri i gba laelae.
Egbe agbaboolu France ti le Argentina jade ni World Cup, pelu amo ayo merin si meta.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…