Home ERÉ ÌDÁRAYÁ France n rojo goolu sile Argentina
ERÉ ÌDÁRAYÁ - June 30, 2018

France n rojo goolu sile Argentina

Egbe agbaboolu France ati Argentina n rojo goolu sile ara won ninu idije to n lo lowolowo bayii ni Russia.
Ni ibere, bi eni kinni ba ti gba boolu wole ni ekeji n da a pada.
Sugbon bayii o, France lo si n gbegbe oroke, pelu ami ayo merin si meji.
Iseju meedogbon (25 minutes) lo ku ki idije naa padi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…