Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Esu n run lori Ronaldo: Uraguay: 1 ; Portugal : 0
ERÉ ÌDÁRAYÁ - June 30, 2018

Esu n run lori Ronaldo: Uraguay: 1 ; Portugal : 0

Abala akoko (first half) ti pari ninu idije boolu laarin Portugal ati Uraguay bayii o.
Uraguay si ti gba boolu kan wole, nigba ti Portugal ko tii ta putu.
Awon agbaboolu naa n sinmi lowo bayii.
Bi idije naa ba lo pari bayii, o je pe Portugal naa n lo sile bii ti Argentina niyen o; to tumo sip e, lowolowo yii, esu n run lori Ronaldo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…