Home Orisirisi WORLD CUP: FIFA maa fun Naijiria ni TWO BILLION NAIRA!
Orisirisi - June 29, 2018

WORLD CUP: FIFA maa fun Naijiria ni TWO BILLION NAIRA!

Bi o tile je pe Super Eagles ti ja kuro ninu idije World Cup to n lo lowo ni Russia, ajo agbaboolu agbaye ko ni je ki won lo lowo ofo o.
Koda owo nla to le ni bilionu meji naira ni FIFA yoo fun Naijiria.
Ni pato, milionu mefa ati egberun lona ogorun dola ($6.1m) ni FIFA maa fun gbogbo awon orile-ede to ja ni ipele kinni idije naa.
Ti a ba se owo naa si naira, o le ni bilionu meji.
Awon to ba ja yoo gba owo to le ni milionu milionu mesan-an dola.
Eni to ba gba ipo keta yoo gba milionu merindinlogun dola. Ipo keji yoo gba milionu mejidinlogun, nigba ti eni to ba gba ife eye naa yoo gba milionu mokanlelogun dola – $21m.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…