Home Orisirisi Liz Anjorin fe ki Buhari gbe idanwo nla siwaju Buhari
Orisirisi - June 29, 2018

Liz Anjorin fe ki Buhari gbe idanwo nla siwaju Buhari

Buhari-2
Bi logbologbo ti tubo n fi Naijiria yii, osere fiimu ti a mo si Liz Anjorin ti gbe idanwo nla kan si iwaju Aare Muhammadu Buhari.
Koda, idanwo naa, gege bi adanwo ni, ki Olorun ma je ki a ri adanwo.
Lori gbogbo ipaniyan to n lo niluu, Liz Anjorin ni ohun ti Buhari ni lati se lati dawo re duro ni ki o tu gbogbo awon ojjelu ati onijibiti ti won gbe ow lo si oke okun ni ona aito sile.
O ni bi ijoba ba ti se bee, wahala yoo kuro ni ilu.
Ibi ti aba naa ti wad a bi idanawo ati adanwo nip e gbogbo eniyan lo mo pe Buhari ko ni fe se bee.
Oba Liz Anjorin ti wa ran Aare l’Odo Oba, Odo Oba kun: ise oba ko see ma je, Odo Oba si niyi, ko see ko si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…