Home Orisirisi Ahmed Musa pada de lati Russia, awon eniyan suuru bo o ni Abuja
Orisirisi - June 29, 2018

Ahmed Musa pada de lati Russia, awon eniyan suuru bo o ni Abuja

5b3694e45281f

ahmed-musa-nigeria-iceland-world-cup-2018_1989qkns0y6sm1wiaophrxyzux
Opo omo Naijiria lo fi ife han agbaboolu Super Eagles ti a mo si Ahmed Musa ni Abuja lonii, nigba to pada de lati Russia.
Inu won dun si i lori bo se gba goolu meji wole Iceland, bi o tile je pe Argentina fun Super Eagles ni Red Card ninu idije World Cup to n lo lowo.
Bi won se n pariwo idunnu le Ahmed Musa lori ni Abuja naa ni won n ba a ya foto Selfie.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…