Fathia Balogun n powe mo awon ore odale
Osere fiimu, Fathia Balogun, to n je Fathia Williams bayyi, ti soro ijinle lori awon ota-bi-ore.
O ni ni toun o, oun ko fe ore ti ko ni itumo si igbesi aye oun.
O ki awn ololufe re lori ero alatagba nilo pe ore yowu ti ko ba kopa Kankan nibi ilosiwaju won, o dara ki won year fun un.
Ohun ti a ko tii mo ni boya eni kan to je ore Fathia ti se aida kan si i ni, to wa n powe mo onitohun.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…