Home Orisirisi Ighalo se akoba fun Super Eagles
Orisirisi - June 26, 2018

Ighalo se akoba fun Super Eagles

Ighalo se akoba fun Super Eagles
Egbe agbaboolu Argentina ti le Super Eagles kuro ninu idije World Cup ti odun yii.
Ami ayo meji ni won ni, nigba ti Naijeria ni eyo kan soso.
Bi o tile je pe Argentina ko fun Ahmed Musa laaye lati da won low obo se se fun Iceland, Odion Ighalo ri awon anfaani kan ti ko mulo daadaa
Eemeji ototo lo ku oun ati golikipa Argentina, sugbon to se anfaani naa basubasu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…